Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò bí Jésù ṣe ran àwọn èèyàn lọ́wọ́ láti di ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ àti báwa náà ṣe lè fara wé e. A tún máa jíròrò àwọn apá kan nínú ìwé tuntun náà Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! A dìídì ṣe ìwé yìí kó lè ran àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì wa lọ́wọ́ kí wọ́n lè tẹ̀ síwájú débi tí wọ́n á fi ṣèrìbọmi.