Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b O tún lè rí àwọn ìrírí nínú (1) Ìwé Ìwádìí fún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà lábẹ́ àkòrí náà “Bíbélì,” wá wo ìsọ̀rí náà “Ìwúlò Bíbélì,” kó o tún wá wo “‘Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà’ (Ọ̀wọ́ àpilẹ̀kọ Ilé Ìṣọ́)” lábẹ́ ìsọ̀rí náà tàbí (2) “Ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò àti Ìrírí” nínú JW Library®.