Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ṣé ó máa ń ṣe ẹ́ bíi pé kò sẹ́ni tó rí tìẹ rò tàbí pé o ò rẹ́ni fojú jọ? Tó bá jẹ́ bẹ́ẹ̀, jẹ́ kó dá ẹ lójú pé Jèhófà mọ ohun tó ò ń bá yí, ó sì ṣe tán láti ràn ẹ́ lọ́wọ́. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò ohun tó o lè ṣe. Àá tún jíròrò ohun tí ẹnì kọ̀ọ̀kan wa lè ṣe láti ran àwọn ará tó nírú ìṣòro yìí lọ́wọ́.