Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b ÀLÀYÉ Ọ̀RỌ̀: Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa sọ̀rọ̀ nípa ìgbéraga, ìyẹn ni pé kéèyàn máa ronú pé òun sàn ju àwọn míì lọ. A tún máa sọ̀rọ̀ nípa ojúkòkòrò, ìyẹn kéèyàn máa wá bí á ṣe ní owó rẹpẹtẹ, kó má ní àmójúkúrò nínú àwọn nǹkan tara títí kan ìbálòpọ̀. Ó tún kan kéèyàn máa wá ipò lójú méjèèjì.