Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
d ÀWÒRÁN: Ìgbéraga ló mú kí áńgẹ́lì kan àti Ọba Ùsáyà ṣìwà hù. Ojúkòkòrò ló mú kí Éfà jẹ èso igi tí Ọlọ́run kà léèwọ̀, òun ló mú kí Dáfídì bá Bátí-ṣébà ìyàwó oníyàwó sùn, òun náà ló sì mú kí Júdásì máa jalè.