Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Gbogbo wa la ní ìṣòro kan tá à ń bá yí. Kò sì sóhun tá a lè ṣe sí i àfi ká fara dà á. Àmọ́, àwa nìkan kọ́ la ní ohun tá à ń fara dà, Jèhófà náà ń fara da ọ̀pọ̀ nǹkan. Torí náà nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò mẹ́sàn-án lára àwọn nǹkan tí Jèhófà ń fara dà. A tún máa rí àwọn ohun tá à ń gbádùn torí pé Jèhófà ń fara dà á, àá sì rí bá a ṣe lè fara wé e.