Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Ní ọ̀pọ̀ iléèwé, wọn kì í kọ́ àwọn ọmọ pé Ọlọ́run ló dá gbogbo nǹkan. Àwọn olùkọ́ kan ronú pé táwọn bá ṣe bẹ́ẹ̀, ṣe ló máa dà bí ìgbà táwọn fẹ́ fipá mú káwọn ọmọ gba Ọlọ́run gbọ́.