ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ

Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé

a A nífẹ̀ẹ́ Jèhófà gan-an, a sì fẹ́ ṣe gbogbo ohun tá a lè ṣe lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn ẹ̀. Ìyẹn lè mú kó wù wá láti ṣe púpọ̀ sí i lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù tàbí ká máa sapá láti ní ojúṣe míì nínú ìjọ. Àmọ́, tí ọwọ́ wa ò bá tẹ àǹfààní iṣẹ́ ìsìn náà pẹ̀lú gbogbo ìsapá wa ńkọ́? Kí la lè ṣe tá ò fi ní dẹwọ́ lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn wa tí àá sì máa láyọ̀ nìṣó? A máa rí ìdáhùn sáwọn ìbéèrè yìí nínú àpèjúwe tálẹ́ńtì tí Jésù ṣe.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́