Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ọ̀dọ̀ Jèhófà ni gbogbo nǹkan rere ti wá, gbogbo èèyàn ló máa ń ṣoore fún títí kan àwọn èèyàn burúkú. Àmọ́ inú ẹ̀ máa ń dùn láti ṣoore fún àwọn tó ń sìn ín tọkàntọkàn. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò bí Jèhófà ṣe ń ṣoore fáwọn ìránṣẹ́ rẹ̀. Àá tún jíròrò bí àwọn tó bá ṣe púpọ̀ sí i lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn wọn ṣe máa rí oore Jèhófà lọ́nà tó ṣàrà ọ̀tọ̀.