Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ẹni iyì làwọn àgbàlagbà tó wà láàárín wa, wọ́n sì ṣeyebíye gan-an. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò bá a ṣe lè túbọ̀ mọyì wọn, àá sì rí bá a ṣe lè jàǹfààní látinú ìrírí àti ọgbọ́n tí wọ́n ní. Yàtọ̀ síyẹn, àpilẹ̀kọ yìí máa jẹ́ kó túbọ̀ dá àwọn àgbàlagbà yìí lójú pé ètò Jèhófà mọyì wọn gan-an, àá sì rí ipa ribiribi tí wọ́n ń kó nínú ìjọsìn Jèhófà.