Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Inú wa dùn pé a ní ọ̀pọ̀ àwọn ọ̀dọ́kùnrin àtàwọn ọ̀dọ́bìnrin tí wọ́n ń ṣe gbogbo ohun tí wọ́n lè ṣe lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn Jèhófà. Láìka ibi tí wọ́n dàgbà sí àti àṣà ìbílẹ̀ wọn, àwọn àgbàlagbà lè ran àwọn ọ̀dọ́ lọ́wọ́ kí wọ́n lè lo gbogbo okun wọn lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn Jèhófà.