Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò òye tuntun tá a ní nípa Hágáì 2:7. A tún máa kẹ́kọ̀ọ́ nípa bá a ṣe lè máa kópa nínú iṣẹ́ tó ń mi gbogbo orílẹ̀-èdè jìgìjìgì. Àá tún rí bí iṣẹ́ yìí ṣe ń mú káwọn kan ṣèpinnu tó tọ́ táwọn míì sì ń ta kò wá.