Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
d ÀWÒRÁN: Hágáì rọ àwọn èèyàn Ọlọ́run pé kí wọ́n má rẹ̀wẹ̀sì lẹ́nu iṣẹ́ tẹ́ńpìlì tí wọ́n ń kọ́. Àwa èèyàn Ọlọ́run lónìí náà ń fìtara kéde ìhìn rere Ìjọba Ọlọ́run fáwọn èèyàn. Tọkọtaya kan ń kéde ìmìtìtì kan tó máa wáyé lọ́jọ́ iwájú fáwọn èèyàn.