Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ìrònúpìwàdà tó wá látọkàn kọjá kéèyàn kàn sọ pé òun kábàámọ̀ ohun tí òun ṣe. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa sọ̀rọ̀ nípa àpẹẹrẹ Ọba Áhábù, Ọba Mánásè àti ọmọ onínàákúnàá tó wà nínú àkàwé tí Jésù ṣe. Àpẹẹrẹ wọn máa jẹ́ ká mọ̀ tí ẹnì kan bá ronú pìwà dà tọkàntọkàn. A tún máa jíròrò ohun táwọn alàgbà gbọ́dọ̀ gbé yẹ̀ wò kí wọ́n lè mọ̀ bóyá ẹnì kan tó dẹ́ṣẹ̀ tó burú jáì nínú ìjọ ti ronú pìwà dà látọkàn wá.