Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé c ÀWÒRÁN: Ọba Mánásè sọ fáwọn ìránṣẹ́ ẹ̀ pé kí wọ́n fọ́ àwọn ère òrìṣà tó gbé sínú tẹ́ńpìlì.