Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé c ÀWÒRÁN: Látorí òrùlé, bàbá náà rí ọmọ rẹ̀ onínàákúnàá tó ń pa dà bọ̀ wálé, ó sì sáré lọ pàdé rẹ̀.