Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Gbogbo wa là ń fojú sọ́nà fún ìgbà tí ètò àwọn nǹkan yìí máa dópin. Àmọ́ láwọn ìgbà míì, ó lè máa ṣe wá bíi pé ṣé a máa ní ìgbàgbọ́ tó lágbára tó láti kojú àwọn ìṣòro tó máa wáyé lọ́jọ́ iwájú. Torí náà nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa sọ̀rọ̀ nípa ìrírí àwọn ará wa àtàwọn nǹkan pàtó tá a lè ṣe táá jẹ́ kí ìgbàgbọ́ wa túbọ̀ lágbára báyìí.