Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Kí ni ìfẹ́ tí kì í yẹ̀? Àwọn wo ni Jèhófà máa ń fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí, báwo sì ni àwọn tó fi ìfẹ́ yìí hàn sí ṣe ń jàǹfààní rẹ̀? A máa dáhùn àwọn ìbéèrè yìí nínú àpilẹ̀kọ méjì àkọ́kọ́ tá a ti máa jíròrò ànímọ́ tó ṣàrà ọ̀tọ̀ yìí.