Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c ÀWÒRÁN: Gbogbo aráyé ni Jèhófà ń fi ìfẹ́ hàn sí títí kan àwa ìránṣẹ́ rẹ̀. Àwọn àwòrán tó wà lókè àwọn èèyàn yẹn ń fi ìfẹ́ tí Ọlọ́run ní sí wa hàn. Èyí tó ṣe pàtàkì jù lára nǹkan tí Ọlọ́run fún wa yìí ni Jésù ọmọ rẹ̀ tó kú nítorí wa.