Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
d ÀWÒRÁN: Jèhófà máa ń fi ìfẹ́ àrà ọ̀tọ̀ hàn sáwọn tó di ìránṣẹ́ rẹ̀ tí wọ́n sì ní ìgbàgbọ́ nínú ẹbọ ìràpadà Jésù. Yàtọ̀ sí pé àwa ìránṣẹ́ Jèhófà ń gbádùn ìfẹ́ tó ń fi hàn sí gbogbo aráyé, a tún ń gbádùn ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ tó ń fi hàn sí wa. Àwọn kan lára nǹkan tá à ń gbádùn ló wà nínú àwọn àwòrán yẹn.