ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ

Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé

a A nífẹ̀ẹ́ Jèhófà gan-an, a sì ń fẹ́ láti máa ṣe ìfẹ́ rẹ̀. Torí pé Jèhófà jẹ́ mímọ́, ó ń fẹ́ káwa tá à ń jọ́sìn ẹ̀ náà jẹ́ mímọ́. Ǹjẹ́ ó ṣeé ṣe káwa èèyàn aláìpé jẹ́ mímọ́? Bẹ́ẹ̀ ni, ó ṣeé ṣe. Ẹ jẹ́ ká fara balẹ̀ ṣàyẹ̀wò ìmọ̀ràn tí àpọ́sítélì Pétérù gba àwọn tí wọ́n jọ jẹ́ Kristẹni àti ìtọ́sọ́nà tí Jèhófà fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì àtijọ́. Àwọn nǹkan yẹn máa jẹ́ ká mọ bá a ṣe lè jẹ́ mímọ́ nínú gbogbo ìwà wa.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́