Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Bó tiẹ̀ jẹ́ pé àwa Kristẹni ò tẹ̀ lé Òfin Mósè mọ́, síbẹ̀, òfin yẹn mẹ́nu kan àwọn nǹkan tó yẹ ká máa ṣe àtèyí tí kò yẹ ká ṣe. Tá a bá ń kẹ́kọ̀ọ́ nípa wọn, ó máa ràn wá lọ́wọ́ láti fìfẹ́ hàn sáwọn èèyàn, ó sì tún máa jẹ́ ká ṣe ohun táá múnú Ọlọ́run dùn. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò àwọn ẹ̀kọ́ tó wà nínú Léfítíkù orí kọkàndínlógún (19) àtàwọn àǹfààní tó máa ṣe wá.