Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Àwọn ẹsẹ míì nínú Léfítíkù orí 19 tá ò mẹ́nu kàn nínú àpilẹ̀kọ méjèèjì yìí sọ pé ojúsàájú, bíba orúkọ èèyàn jẹ́ àti jíjẹ ẹ̀jẹ̀ kò dáa, ó sì tún sọ pé lílọ́wọ́ nínú iṣẹ́ òkùnkùn, wíwádìí ọ̀rọ̀ lọ́dọ̀ woṣẹ́woṣẹ́ àti ìṣekúṣe kò dáa.—Léf. 19:15, 16, 26-29, 31.—Wo “Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé” tó wà nínú ìwé yìí.