Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Jésù gbà wá níyànjú pé ká gba ẹnu ọ̀nà tóóró tó lọ sí ìyè àìnípẹ̀kun. Ó tún sọ fún wa pé ká máa wá àlàáfíà pẹ̀lú àwọn tá a jọ ń sin Jèhófà. Àwọn ìṣòro wo ló ṣeé ṣe ká kojú tá a bá fẹ́ fi ìmọ̀ràn Jésù sílò, báwo la sì ṣe lè borí ẹ̀?