Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
d ÀWÒRÁN: Tá a bá ń tẹ̀ lé àwọn ìlànà Jèhófà bá a ṣe wà lójú ọ̀nà “tóóró” tó lọ sí ìyè àìnípẹ̀kun, a ò ní máa wo àwòrán ìṣekúṣe, a ò ní máa kẹ́gbẹ́ pẹ̀lú àwọn tó máa jẹ́ ká ṣèṣekúṣe, a ò sì ní gbà fáwọn tó ní dandan ká lọ sílé ẹ̀kọ́ gíga.