Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé e ÀWÒRÁN: Lẹ́yìn táwọn ọmọ Ísírẹ́lì fi Íjíbítì sílẹ̀, Jèhófà fi mánà bọ́ wọn, kò sì jẹ́ kí aṣọ wọn gbó.