Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa sọ̀rọ̀ nípa ìdí tó fi yẹ ká túbọ̀ fọkàn tán Jèhófà àtàwọn tó ń ṣàbójútó nínú ètò rẹ̀ lórí ilẹ̀ ayé. A tún máa sọ̀rọ̀ nípa àǹfààní tá a máa rí tá a bá fọkàn tán wọn báyìí àti bí èyí ṣe lè múra wa sílẹ̀ de àwọn ìṣòro ọjọ́ iwájú.