Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àwa èèyàn Jèhófà mọ̀ pé ó ṣe pàtàkì ká máa tẹ̀ lé ìmọ̀ràn Bíbélì. Síbẹ̀, kì í ṣe gbogbo ìgbà ló máa ń rọrùn láti gba ìmọ̀ràn. Kí nìdí tó fi rí bẹ́ẹ̀? Kí ló sì máa jẹ́ ká jàǹfààní látinú ìmọ̀ràn tí wọ́n bá fún wa?