Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Jésù ò mọ tara ẹ̀ nìkan, bó ṣe máa kọ́kọ́ gbọ́ tàwọn míì ló máa ń rò. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa sọ̀rọ̀ nípa bá a ṣe lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ ẹ̀. A tún máa sọ̀rọ̀ nípa àwọn àǹfààní tá a máa rí tá a bá ń ran àwọn èèyàn lọ́wọ́ bíi ti Jésù.