Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b ÀWÒRÁN: Arákùnrin ọ̀dọ́ kan tó ń jẹ́ Dan ń wo àwọn alàgbà méjì tó wá kí bàbá ẹ̀ nílé ìwòsàn. Ohun táwọn alàgbà yẹn ṣe wọ Dan lọ́kàn, ìdí nìyẹn tóun náà fi fẹ́ ran àwọn èèyàn lọ́wọ́ nínú ìjọ. Arákùnrin ọ̀dọ́ kan tó ń jẹ́ Ben ń wo bí Dan ṣe ń bójú tó àwọn míì. Àpẹẹrẹ Dan mú kí Ben náà bẹ̀rẹ̀ sí í tún Gbọ̀ngàn Ìjọba ṣe.