Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a A gbọ́dọ̀ ṣe àwọn àyípadà kan ká tó lè ṣèrìbọmi. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa rí àwọn ìwà àtijọ́ tó yẹ ká bọ́ sílẹ̀, ìdí tó fi yẹ ká bọ́ wọn sílẹ̀ àti bá a ṣe lè ṣe é. Nínú àpilẹ̀kọ tó kàn, a máa rí bá a ṣe lè máa gbé ìwà tuntun wọ̀ kódà lẹ́yìn tá a ti ṣèrìbọmi.