Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b ÀLÀYÉ Ọ̀RỌ̀: Téèyàn bá “bọ́ ìwà àtijọ́ sílẹ̀,” kò ní máa hùwà tí inú Jèhófà ò dùn sí. Ó sì yẹ kó ti bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe àwọn àyípadà tó yẹ kó tó ṣèrìbọmi.—Éfé. 4:22.