Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé g ÀWÒRÁN: Bá a ṣe máa ń bọ́ aṣọ tó ti gbó sọ nù, bẹ́ẹ̀ náà ló ṣe yẹ ká ṣiṣẹ́ kára láti jáwọ́ nínú àwọn ìwà burúkú.