Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Gbogbo wa la máa jàǹfààní tá a bá ń kíyè sí ohun táwọn míì ń ṣe lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn Jèhófà. Àmọ́, kò yẹ ká máa fi ara wa wé àwọn ẹlòmíì. Torí náà, àpilẹ̀kọ yìí máa jẹ́ ká rí bá a ṣe lè máa láyọ̀ nìṣó lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn Jèhófà. Ó tún máa jẹ́ ká rí ìdí tí kò fi yẹ ká máa gbéra ga tá a bá rí i pé à ń ṣe ju àwọn míì lọ àti ìdí tí kò fi yẹ ká rẹ̀wẹ̀sì táwọn míì bá ń ṣe jù wá lọ.