Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé d ÀWÒRÁN: Kí bàbá kan lè mọ àwọn ọ̀rẹ́ ọmọ ẹ̀, ó ń bá ọmọ ẹ̀ àti ọ̀rẹ́ ọmọ ẹ̀ gbá bọ́ọ̀lù alápẹ̀rẹ̀.