Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c ÀLÀYÉ Ọ̀RỌ̀: “Ìrònúpìwàdà” túmọ̀ sí kéèyàn yí èrò ẹ̀ pa dà, kó kábàámọ̀ gidigidi nípa bó ṣe lo ìgbésí ayé ẹ̀, kó kábàámọ̀ ìwà àìtọ́ tó hù tàbí ohun tó kọ̀ láti ṣe. Ìrònúpìwàdà tó wá látọkàn máa ń fi hàn pé ẹnì kan ti yí ìwà ẹ̀ pa dà.