Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé e ÀWÒRÁN: Àwọn òbí ọ̀dọ́kùnrin kan ò fẹ́ kó sin Jèhófà, àmọ́ ó dá a lójú pé Jèhófà ò ní fi òun sílẹ̀.