Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b ÀLÀYÉ Ọ̀RỌ̀: Ọ̀rọ̀ Hébérù tí wọ́n tú sí “gbẹ́kẹ̀ lé” sábà máa ń túmọ̀ sí kéèyàn “dúró de” nǹkan, kó sì nírètí pé ọwọ́ òun máa tẹ nǹkan ọ̀hún. Ó tún lè túmọ̀ sí kéèyàn fọkàn tán ẹnì kan tàbí kó gbára lé onítọ̀hún.—Sm. 25:2, 3; 62:5.