Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé e ÀWÒRÁN: Jóòbù fara da àwọn àdánwò tó dé bá a. Òun àti ìyàwó ẹ̀ ń sọ̀rọ̀ nípa bí Jèhófà ṣe bù kún ìdílé wọn.