Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àkókò táwọn àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì ń ṣẹ là ń gbé yìí! Ọ̀pọ̀ àsọtẹ́lẹ̀ inú Bíbélì fi hàn pé Ìjọba Ọlọ́run ti ń ṣàkóso. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa wo díẹ̀ lára àwọn àsọtẹ́lẹ̀ náà. Ìyẹn á jẹ́ kí ìgbàgbọ́ wa nínú Jèhófà túbọ̀ lágbára, á sì tún jẹ́ kí ọkàn wa balẹ̀ ká sì gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà nísinsìnyí àti lọ́jọ́ iwájú.