Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a A ò lè mọyì ohun tó wà nínú Bíbélì tá ò bá lóye àsọtẹ́lẹ̀ tó wà nínú Jẹ́nẹ́sísì 3:15. Tá a bá gbé àsọtẹ́lẹ̀ yìí yẹ̀ wò, á mú kí ìgbàgbọ́ wa nínú Jèhófà lágbára, á sì jẹ́ kó túbọ̀ dá wa lójú pé ó máa mú gbogbo ìlérí ẹ̀ ṣẹ.