Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé c ÀWÒRÁN: Tọkọtaya kan lọ sí apá ibì kan lórílẹ̀-èdè wọn kí wọ́n lè ṣèrànwọ́ fáwọn tí àjálù dé bá.