Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Bíbélì kìlọ̀ fún wa pé àwọn kan wà nínú ìjọ tí kò yẹ ká fọkàn tán. (Júùdù 4) Lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan, àwọn èké arákùnrin máa ń sọ “àwọn ọ̀rọ̀ békebèke” kí wọ́n lè ṣi àwọn ará lọ́nà. (Ìṣe 20:30) A ò gbọ́dọ̀ fọkàn tán irú àwọn ẹni bẹ́ẹ̀ tàbí ká fetí sí wọn.