Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Tá a bá mọ ẹnì kan nínú ìjọ tó dá ẹ̀ṣẹ̀ ńlá, ó yẹ ká gbà á níyànjú pé kó lọ sọ fáwọn alàgbà kí wọ́n lè ràn án lọ́wọ́. Tí kò bá ṣe bẹ́ẹ̀, àwa fúnra wa máa lọ sọ ọ̀rọ̀ náà fáwọn alàgbà torí a fẹ́ jẹ́ olóòótọ́ sí Jèhófà àti ìjọ.