Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Nínú Jòhánù 5:28, 29, Jésù sọ̀rọ̀ nípa “àjíǹde ìyè” àti “àjíǹde ìdájọ́.” Torí náà nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò òye tuntun tá a ní nípa ẹsẹ Bíbélì yìí. A máa mọ ohun tí àjíǹde méjèèjì yìí jẹ́, àá sì tún mọ àwọn tí àjíǹde méjèèjì yìí kàn.