Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Jèhófà ti bẹ̀rẹ̀ sí í kọ orúkọ àwọn èèyàn sínú ìwé yìí “látìgbà ìpìlẹ̀ ayé,” ìyẹn látìgbà ayé àwọn èèyàn tí wọ́n lè jàǹfààní ẹbọ ìràpadà Jésù. (Mát. 25:34; Ìfi. 17:8) Torí náà, ó hàn gbangba pé ọkùnrin olóòótọ́ àkọ́kọ́ tí orúkọ ẹ̀ wà nínú ìwé náà ni Ébẹ́lì.