Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ká lè máa fara da ìṣòro wa ká sì jẹ́ olóòótọ́ láwọn ọjọ́ ìkẹyìn yìí, a gbọ́dọ̀ máa fọkàn tán Jèhófà àti ètò rẹ̀. Àmọ́ Èṣù máa ń fẹ́ lo àwọn ìṣòro tó dé bá wa láti mú ká má fọkàn tán Jèhófà àti ètò ẹ̀ mọ́. Torí náà nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa sọ̀rọ̀ nípa ìṣòro mẹ́ta tí Èṣù máa ń lò àtàwọn nǹkan tá a lè ṣe ká má bàa fi Jèhófà àti ètò ẹ̀ sílẹ̀.