ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ

Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé

a Ní Tuesday, April 4, 2023, àìmọye èèyàn kárí ayé ló máa kóra jọ láti ṣe Ìrántí Ikú Kristi. Ọ̀pọ̀ ló jẹ́ pé ìgbà àkọ́kọ́ tí wọ́n máa wá nìyí. Àwọn kan tí wọ́n ti di aláìṣiṣẹ́mọ́, tó sì ti pẹ́ tí wọ́n ti wá sí Ìrántí Ikú Kristi náà máa wà níbẹ̀. Àwọn nǹkan kan lè má jẹ́ kó rọrùn fáwọn kan láti wá, àmọ́ wọ́n ṣì máa ṣe gbogbo ohun tí wọ́n lè ṣe kí wọ́n lè wà níbẹ̀. Ohun yòówù kó jẹ́, mọ̀ dájú pé inú Jèhófà máa dùn sí ẹ tó o bá wá.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́