Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Nígbà tí Jésù ṣèrìbọmi, tí Jèhófà sì fẹ̀mí mímọ́ yàn án, Jèhófà jẹ́ kó rántí àwọn nǹkan tó ti kọ́ lọ́run kó tó wá sáyé.—Mát. 3:16.