Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa sọ̀rọ̀ nípa bá ò ṣe ní jẹ́ kí ohunkóhun ba àjọṣe àwa àti Jèhófà jẹ́ bá a ṣe ń wo àwọn nǹkan tó ń ṣẹlẹ̀ lágbàáyé. Yàtọ̀ síyẹn, a máa sọ̀rọ̀ nípa bá a ṣe lè máa kíyè sára wa àti bó ṣe yẹ ká máa lo àkókò wa lọ́nà tó dáa jù lọ.